Gomina ipinlẹ Ọyọ, Onimọ ẹrọ Seyi Makinde ti jẹ ko di mimọ pe ko si aniani, o ti di dandan ki awọn eeyan ti wọn fẹsun kan pe wọn lọwọ ninu iku awọn ọmọde marundinlogoji nibi iṣẹlẹ itẹra-ẹni pa to waye nibi eto apejẹ- ifunni-lounjẹ opin ọdun lọfẹ ti olori …
Ka si »