Ọrọ to n lọ laarin ilu nipa awọ ohun rogbodiyan tonise nipa Imam Agba ilẹ Ogbomọsọ ni awọn eeyan kan ti bẹrẹ sini sigbọ, fi oju ọtọ wo bayi o. Ọpọ eeyan lo n fi ọrọ naa kọ Sọun tilẹ Ogbomọsọ, Ọba Ghandi Afọlabi Ọlaoye lọrun pe Kabiesi fẹ yọ …
Ka si »