Iroyin pajawiri - Ẹ sinmi bíba Ọba lórúkọ jẹ́, Ọba Ghandi Afọlabi Ọlaoye kòsí nídi a n yọ Imam Àgbà ilẹ̀ Ògbọ́mọ̀sọ́ nípò.
- Ọ̀dájú Ọkùnrin kan dáná sun ìyàwó rẹ̀ lásìkò tí wọn n ja.
- Ọ̀rọ̀ akọ àti abo tí Trump sọ nípa rẹ̀ kò kàn èmi o torí obìnrin ni mí, mo sì ní ẹ̀rì tó dájú – Bobrisky
- Ìmáàmù Agba Ogbomoso tu ba o, o rawọ-ẹbẹ sí Sọun tilẹ Ògbómọ̀ṣọ́, Ọba Ghandi Afọlabi, pe ko má bínú gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ t’oun bá ṣẹ̀
- Lateef Adedimeji: Àgàn lọ̀pọ̀ n pe Mo-Bimpe aya mi, àmọ́ nse ni mo kọtí ikún.
- Ilumọnka, gbajúgbajà Olórin fuji nn K1 De Ultimate pàdánu iya ẹ lẹ́ni ọdún Márùnlélọ́gọ́run (105)
- Olorì Damilọla dákú lóbá dèro ilé ìwòsàn látàri bí Portable tún se b’ọ́nà mi yọ si
- Wàhálà, Ija tun bẹ silẹ laarin Ifọn àti Ilobu, ìjọba ipinlẹ Osun kéde kónílé o gbélé lawọn ilu mejeeji
- Ó màse o, Oriyomi b’omijé lójú lásìkò tó n ba àwọn olólùfẹ́ rẹ sọrọ lẹ́yìn to jade kuro lọ́gbà ẹ̀wọ̀n
- Ọpẹ oo, Ilé ẹjọ́ gba béèlì Oriyomi, Naomi ati Ọga agba ile-ẹkọ gírámà Abdullahi, pẹlu ìkìlọ̀ ńlá fún Oriyomi
- Olùkọ tó n fi’gbaju, Igbamu kọ akẹ́kọ̀ọ́, ọmọ ọdún mẹta ti dero Ọgbà ẹ̀wọ̀n Kiríkirì