Iroyin pajawiri

Uncategorized

Olùkọ tó n fi’gbaju, Igbamu kọ akẹ́kọ̀ọ́, ọmọ ọdún mẹta ti dero Ọgbà ẹ̀wọ̀n Kiríkirì

Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá orileede Naijiria ti tari olukọ ileewe alakọbẹrẹ kan, Stella Nwadigo, ẹni to ko igbamu-igbaju bo akẹkọọ, ọmọ ọdun mẹta kan torukọ rẹ n jẹ Abayọmi Michael lọ si ile ẹjọ lati lọ kawọ pọnyin rojọ ohun ti o ri to fi n gba ọmọ loju. Agbẹnusọ ọlọpaa ni …

Ka si »

Lẹyìn ọdún mẹta ti Alaafin àná ti wàjà Owoade Gomins Makinde buwọ́lù ìyànsípò Owoade gẹ́gẹ́ bí Alaafin Ọ̀yọ́.

Gómìna ipinlẹ Ọyọ onimọ-ẹrọ Seyi Makinde, ti buwọ́lù iyansipo Ọmọọba Abimbola Ọwọade gẹgẹ bí Alaafin Ọyọ tuntun ti yóò gori apeere awọn baba nla rẹ. Ikede ọhun lo jẹyọ jade ninu atẹjade kan to jẹ gbigbe jade sita l’ọjọ Ẹti Friday, lat’ọwọ Kọmisọna f’eto iroyin ati ilanilọyẹ, Ọmọ ọba Dotun …

Ka si »

l’Ogbomọsọ, Kọntena (Container) ẹ̀yìn ọkọ̀ nla kan rélu kẹ̀kẹ́ Maruwa t’oun t’àwọn èrò inú rẹ lorita Takie, Ògbómọ̀sọ́.

Iṣẹlẹ ìjàmbá ọkọ nla ọhun lo waye lorita Takie, nilu Ogbomọsọ ni nkan bi owurọ ọjọ Isẹgun Tuesday, ọjọ keje, oṣù kínní, ọdun 2025. Nse ni ọkọ tirela ẹlẹyin Kọntana naa sọ bireki-ijanu rẹ nù, to sì lọ kọlu awọn èèyàn, debi ti kọntena ẹyin rẹ wolu kẹkẹ maruwa ẹlẹsẹ …

Ka si »

Ọlọrun ò fẹ́kú ẹlẹ́sẹ̀ bìkòse ìrònúpìwàdà, àmọ́ ẹni tó sọ àwòrán mi d’Alhaji ó ti yàn láti parun Pásítọ̀ Adeboye sọ bẹ.

Oluṣọaguntan agba naa fun ijọ The Redeemed Christian Church of God, RCCG, Pasitọ Enoch Adeboye lo sọ asọtẹlẹ yi nipa awọn kan to gbe aworan atọwọda imọẹrọ AI eyi to ṣe afihan rẹ gẹgẹ bi arinrinajo Hajj lọdun to kọja. Pasitọ Adeboye wa ṣalaye lasiko to n ba awọn ọmọ …

Ka si »

Pasitọ Adeboye, Bíṣọ́ọ̀bù Oyedepo, Alufa Kumuyi, at’awọn ìránsẹ́ Ọlọrun mii ti sọ àwọn àsọtẹ́lẹ̀ nípa ọdún tuntun 2025 yoo se ri.

Ni ọdọọdun Ọpọ Àwọn èèyàn tó ní afojusun at’awọn iransẹ Ọlọrun lo ma n woye, sọ awọn orisirisi asọtẹlẹ tó nikimi, bẹrẹ lati aisun ọdún tuntun. Gbogbo awọn èèyàn yi lo sí má n fi ọrọ ayé àti ìrìnàjò wọn lè Oluwa lọwọ lọdun tuntun, wọn yóò wa ọna lati …

Ka si »

No going back nifá tí wọn da fún wa o, a sí duro lórí ìdásílẹ̀ Yorùbá Nation – Oloye Sunday Igboho lo sọ bẹ

Oloye Sunday Adeyemo, ti ọpọ èèyàn mọ sí Sunday Igboho, Igboho Òòsà, ẹni ti i se Ajijagbara fún idasilẹ ati ominira Yoruba Nation, ti ranṣẹ ikinni ku ọdun tuntun si awọn èèyàn ọmọ Yorùbá l’ọkunrin ati l’obinrin, nile-loko ati lẹyìn odi titi d’ooke-okun. Nipasẹ Agbẹnusọ rẹ, Olayọmi Koiki, ni Oloye …

Ka si »

Ẹ̀yin Abiamọ o, ẹ má jẹ ki wọ́n pa Naomi o, olúọmọ ló jẹ́ fún mi. – Ìyá t’obi Olorì Naomi lo rawọ́-ẹ̀bẹ̀ bẹ t’omijé-lójú.

Pasitọ Olufunmilayo Ogunseyi, iyẹn mama to bi Olori tẹlẹ fun Ọọni ifẹ, Naomi Silekunola, ti fi omije bẹbẹ nipa ọmọ rẹ, ti o wa lọgba ẹwọn o ni ki gbogbo abiamọ aye ma jẹ ki wọn pa Naomi oun lọmọ tori pe olu ọmọ oun lo jẹ. Ninu fọnran fidio …

Ka si »