Iroyin pajawiri

Láwùjọ Òsèré

Wọ̀nyí ni bí nkan se lọ níbi ètò Ìsìnkú Sheik Muhideen n’Ibadan

Ero pitimu nibi eto isinku ilumọọka alfa to tun jẹ olukọ ẹsin Islam, oniwaasi Sheikh Muyideen Ajani Bello, nile rẹ to wa lagbegbe Akobọ niluu Ibadan. Owurọ ọjọ Ẹti Friday ni iroyin gbe e jade pe Alhaji Sheik Muyideen Bello jade laye. Lati aarọ ọjọ Ẹti yii naa ni ọpọ …

Ka si »

Eyi ni ohun tó ṣokùnfà ikú gbajúmọ̀ òṣèré tíátà krìstẹ́nì Korede Are ‘Baba Gbenro

Ọpọ àwọn oloolufẹ lo ti wọn fẹ gbajumọ osere naa lo ti n ṣedaro Dokita Moses Korede Arẹ ẹni ti ọpọ èèyàn mọ si Baba Gbenro to doloogbe lana Ọjọbọ Thursday, ọjọ kẹrinla oṣu Kọkanla ọdun 2024 yii. Iyalẹnu nla ni iku gbajumọ osere kristiẹni ọhun Baba Gbenro jẹ fun …

Ka si »

Aunty Ramota bèèrè fún ìrànwọ́ owo lọ́wọ́ àwọn èèyàn ọmọ orileede Nàìjíria nótorí ìlera rẹ̀

O ma se o, Fọnran fídíò kan to jade loju opo itakun ayelujara Instagram lo ti ṣafihan bi gbajumọ oṣerebinrin onitiata nní, Ramota Adetu, ti ọpọ èèyàn mọ si Aunty Ramota ṣe n pe fun iranlọwọ àwọn eeyan ọmọ Naijiria pe oun ko ni ile lori mọ. Ninu fọnran fídíò …

Ka si »

Akọni Ọmọ ni ọmọbìnrin mi tó d’ologbe, ikú rẹ bàmí lọ́kàn jẹ́ púpọ̀, Saidi Balogun sọ̀rọ̀ lórí ikú Zeenat Balógun ọmọ rẹ̀.

Gbajugbaja oṣere tiata Yoruba, Saidi Balogun, ti ṣapejuwe ọmọbinrin rẹ, Zeenat Balogun to ku laipẹ yii gẹgẹ bii akọni eeyan. Balogun sọrọ yii ninu atẹjade kan to fi sita loju opo Instagram rẹ lọjọ Aiku Sunday. Ni owurọ ọjọ Ẹti Friday, ọjọ karun un, oṣu Kẹwaa yii ni ilumọọka oṣere …

Ka si »