Tolani Quadri Oyebamiji ti ọpọ eeyan mọ Sisi Quadri ni iroyin iku rẹ gba ori itakun ayelujara lojọ Ẹti Friday, ọjọ kinni osu kẹta ọdun 2024. Ile ẹkọsẹ Iwosan Fasiti Ladoke Akintọla ni gbajumọ osere ẹlẹẹkẹ eebu naa Sisi Qadri dakẹ si. Gẹgẹ bi iroyin naa ti a gbọ nipasẹ …
Ka si »Ìdílé ẹlẹ́ni mẹ́fà kan d’èrò ilé ìwòsàn ẹnìkan ku lẹ́yìn ti wọn jẹ Àmàlà tan nilu Ògbómọ̀sọ́.
Iroyin naa lo bani lọkan jẹ ti o si ko awọn eeyan agbegbe Temidire lọna ti o lọ silu Ajaawa lọkan soke latari bi idike ẹlẹni mẹfa naa se dero ile iwosan lẹyin ti wọn jẹ Amala tan. Gẹgẹ bi iroyin naa ti a gbọ iya agba kan ti wọn …
Ka si »Lẹ́yìn ọjọ́ kẹta tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ lo jí Ọ̀kànlélọ́gọrin le mẹ́fà, N81.6 Miliọnu ọgá rẹ̀ gbe salọ.
Ọwọ ṣikun awọn agbofinro ọlọpaa ti tẹ obinrin ọmọ ọdọ kan ti wọn pe orukọ rẹ ni Blessing Effiong fẹsun kan pe o ji ẹgbẹrun mọkanlelaadọta dọla owo ọga rẹ gbe salọ. Gẹgẹ bi iroyin naa se fi idi rẹ mulẹ iṣiro owo naa ni Naira lo sunmọ mọkanlelgọrin N81.6 …
Ka si »Nipinlẹ Ondo, Ọkùnrin kan gba ibi tó gbà wáyé padà lọ s’ọ̀run lẹ́yìn to ba ọ̀rẹ́bìnrin rẹ lòpọ̀ tan l’Hoteli.
Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ondo ti kede rẹ pe ọwọ ti tẹ eeyan meji lori iku ọkunrin kan ti orukọ rẹ n jẹ Abiodun Akintomowo niluu Ondo. Arakunrin naa lo padanu ẹmi rẹ lẹyin to ni ibalopọ pẹlu obinrin kan tiise ọrẹbinrin rẹ ti wọn n jọ nse wọlewọde, ni ile …
Ka si »Ìjọba ìpínlẹ̀ Eko ti f’òfin de lílo abọ́ fùlùfúlù àti kòndoro ‘Take-Away’
Ijọba ipinlẹ Eko ti fi ofin de lilo ati pinpin igo onike ati abọ fulufulu ti ọpọ mọ take away mọ ni ipinlẹ naa. Kọmiṣọna ọrọ ayika ati awọn alumọni inu omi, Tokunbo Wahab lo fọrọ naa lede lọjọ Aiku sunday lori itakun ayelujara oju opo X rẹ. Abọ fulufulu …
Ka si »Àwon Òsìsẹ́ Ọgbà-iléèwòsàn gbé Obìnrin alaarẹ kan láti ilé ìwòsàn wọ́n wa gbeju si iwájú ibùsọ̀/shopu ọkọ rẹ̀ nilu Ibadan
Niise lọrọ naa nse ni ni haa hin ti haa hin ọhun si gba enu awon eeyan- araadugbo agbegbe Desalu, Odo-Ona, nilu Ibadan, ni agbegbe Ijọba ibile guusu-iwo-orun Southwest Local Government area, nipinlẹ Oyo, pẹlu ohun ti won foju ri losangan ojo eti Friday, ojo kokandinlogun, osu kinni, ọdun 2024 …
Ka si »