Iroyin pajawiri

Ìròyìn Yàjó Yàjó

Imam àgbà Yunus Ayilara kunlẹ rawọ́ ẹ̀bẹ̀ níwájú Ọba Ghandi Afọlabi Sọ̀ún tilẹ̀ Ògbómọ̀sọ̀.

Ni ko pẹ yi ni ipade idakọnkọ alatilẹkun mọri se kan waye eyi ti Kọmisanna ọlọpaa ipinlẹ Ọyọ le waju rẹ ni olu ileesẹ ọlọpaa ti o wa ni Ẹlẹyẹle nilu Ibadan. Sọun tilẹ Ogbomọsọ Ọba Ghandi Afọlabi Ọlaoye orumọ gẹgẹ kẹta wa ni kalẹ pẹlu agba Oye, Sọbalaje Ọtọlorin, …

Ka si »

Ọwọ tẹ àwon Afurasí ajìjàgbara Odua Nation mérìndínlógún pẹ̀lú ohun ìjà olóró lakoko ti won ya wọ ọgbà ọ́fìsì Gómìnà ipinlẹ Oyo

Niise l’awọn Eeyan kan ti won furasi pe wọn jẹ ọmọ ẹgbẹ Ajijagbara Oodua Nation yawọ inu Ọfisi Gomina nilu Ibadan tiise Olu-ilu ipinle Oyo l’owurọ ọjọ Abameta Satide, ojo ketala, osu kerin, odun 2024 ti a wa yi. Awọn ajijagbara naa ni wọn tun yawọ ile igbimọ aṣofin Oyo, …

Ka si »

Zack Orji o ku o, E yé gbé ìròyìn eléjè kiri – Ààre ẹgbẹ́ àwọn òsèré kùnrin elédè òyìnbó, ìyen Actors Guild of Naijiria AGN, Emeka Rollas lo pariwo síta bẹ.

Lẹnu nkan bi ọjọ mẹta yii ni awuyewuye gba ori itakun-ayelukara kan, pe gbajumọ osere-tiata ọmọ Igbo nni, Zack Orji, ti dagbere f’aye. Eyi ri bẹẹ latari iṣẹ abẹ kan ti wọn kede pe ọkunrin naa nilo lati ṣe ni kiakia, nitori ara rẹ ti ko le lẹnu lọọlọ yii. …

Ka si »

Ọ̀rọ̀ burúkú re nígboro ẹnu, Mo fẹ́ mọ̀ bóyá nǹkan ọmọkùnrin mi ń ṣiṣẹ́ dáadáa ni mo ṣe bá ọmọ ọdún mẹ́ta lòpọ̀

Ọwọ ileesẹ ọlọpaa nipinlẹ Ọyọ, ti ba ọkunrin kan ẹni ọdun mejilelogun Farouk, fun ẹsun pe o fi ipa ba ọmọdebinrin ọmọ ọdun mẹta lopọ. Agbegbe Popo Yemoja nilu Ibadan, ni isẹlẹ naa tigbe sẹlẹ ni alẹ Ọjọbọ Tọside ti o kọja. Gẹgẹ bi iwe iroyin Nigerian Tribune ti salaye, …

Ka si »

Èemọ́n re o, Igbákejì Ọ̀ga Àgbà Ọlọ́pàá, Deputy Commissioner of Police pokùnso, sekúpara rẹ̀ nílu Ògbómọ̀sọ́.

Iyoku ara oku igbakeji ọga agba ọlọpaa naa ni wọn ba ninu ilegbe rẹ nibi ti o pokunso si ninu ilegbe rẹ. Ologbe naa ẹni ti i se igbakeji ọga agba ọlọpaa ti wọn pe orukọ rẹ ni Gbọlahan Oyedemi aladugbo rẹ sọ pe o danikan wale fun ayẹyẹ ọdun …

Ka si »

Ikú ti pa ojú Oba de o, Olúbàdàn tilẹ̀ Ìbàdàn jáde láyé lẹ́yìn ọdún méjì tó gba ọ̀pá àsẹ.

Iroyin iku Olubadan tilu Ibadan, Oba Ọmọwe (Dr.) Moshood Olalekan Balogun, Alli Okunmade ll, ẹni tiise Ọba Ẹlẹẹkejilelogoji 42 ọhun lo jẹ eyi ti o ba ni lẹjafu ni asalẹ ọjọbọ Thursday. Ninu Atẹjade kan to je gbigbe jade lati ọfisi Gomina Ipinle Oyo, Onimo-ero Seyi Makinde l’ọjọbọ Toside lo …

Ka si »