Iṣẹlẹ aburu ọhun lo waye nilu Ibadan, tiise Oluilu ipinlẹ Ọyọ l’ọjọru Wednesday, ọjọ kejidinlogun, osu kejila nibi eto ayẹyẹ opin ọdún awọn ọmọdé ìyẹn Children’s Carnival ti awọn ajọ kan sagbatẹru rẹ. Gẹgẹ bí iroyin naa tí a gbọ, isare girigiri, iwariri awọn ọgọrọ eeyan lo sokunfa iṣẹlẹ laabi …
Ka si »Gbajúmọ̀ olórin fújì nni, Alhaji Rahmon Akanni pàdánù ìyàwó rẹ̀, Alhaja Falilat Rahman
Ọdọ rẹ Ọlọhun lati wa, ọdọ rẹ naa la o pada si, Iyawo Alhaji Rahmon Akanni gbajumọ olorin fuji jade laye. Lowurọ oni ọjọ Isẹgun Tuesday, ọjọ kẹtadinlogun, osu kejila ọdun 2024 yi ni iroyin iku iyawo gbajumọ olorin fuji naa jẹ gbigbe jade lori itakun ayelujara Ikanni Facebook. Alhaji …
Ka si »Awuyewuye bẹ sílẹ̀ latari ìròyìn kan to ni ìjọba àpapọ̀ ti wọ́gilé pápákọ̀ òfúrufú ti wọn fẹ kọ si ìlú Ẹdẹ
Ninu oṣu Kọkanla ọdun yii ni ijọba ipinlẹ Ọṣun kede pe papakọ ofurufu ti wọn gbero lati kọ si Ido-Osun tẹlẹri yoo di gbigbe lọ si ilu Ede. Igbakeji gomina Osun lo fidi ọrọ naa mulẹ lori eto ori redio kan niluu Osogbo, nibẹ lo ti ṣalaye pe ijọba pinnu …
Ka si »Wọ̀nyí ni bí nkan se lọ níbi ètò Ìsìnkú Sheik Muhideen n’Ibadan
Ero pitimu nibi eto isinku ilumọọka alfa to tun jẹ olukọ ẹsin Islam, oniwaasi Sheikh Muyideen Ajani Bello, nile rẹ to wa lagbegbe Akobọ niluu Ibadan. Owurọ ọjọ Ẹti Friday ni iroyin gbe e jade pe Alhaji Sheik Muyideen Bello jade laye. Lati aarọ ọjọ Ẹti yii naa ni ọpọ …
Ka si »Àwọn ọmọ ìlú Òsogbo pariwo sita pe Ọba Jimoh Olanipekun Ataoja tìlú Òsogbo gbọ́dọ̀ forí àpèrè Ọba sílẹ̀ ni o
Awọn eeyan ọmọ ile ọba niluu Osogbo ti pariwo síta pe ki araalu o gba wọn lọwọ Ọba Jimoh Olanipekun Ataoja ilu Osogbo, lori ẹsun pe o n fi awọn ti kii ṣe ọmọ ilu naa jẹ oye. Eyi jẹyọ nibi eto ìwọ́de ifehonuhan kan ti awọn eniyan naa ṣe …
Ka si »Trailer ọkọ̀ nlá akẹ́rù sekúpa Bàbá ẹni ọdún mẹ́rìnlélọ́gọ́rin 84 lójú ọ̀nà Ògbómọ̀sọ́.
Baba ẹni ọdun mẹrinlelọgọrin 84 se kongẹ ọlọjọ nipasẹ ikọlu ti ọkọ nla Trailer kan se si lasiko to n gbiyanju a ti rena sọda sodi keji lopopona Ọyọ s’Ogbomọsọ ladugbo Owolakẹ agbegbe Agric Ogbomọsọ. Gẹgẹ bi ẹni ti isẹlẹ naa soju rẹ se wi, Baba Oloye Joseph Ọkẹowo ti …
Ka si »Eyi ni ohun tó ṣokùnfà ikú gbajúmọ̀ òṣèré tíátà krìstẹ́nì Korede Are ‘Baba Gbenro
Ọpọ àwọn oloolufẹ lo ti wọn fẹ gbajumọ osere naa lo ti n ṣedaro Dokita Moses Korede Arẹ ẹni ti ọpọ èèyàn mọ si Baba Gbenro to doloogbe lana Ọjọbọ Thursday, ọjọ kẹrinla oṣu Kọkanla ọdun 2024 yii. Iyalẹnu nla ni iku gbajumọ osere kristiẹni ọhun Baba Gbenro jẹ fun …
Ka si »Àràbà kan tún wo láwùjọ àwọn gbajúmọ̀ òsèré Bọbọ B jáde láyé
Araba miran tun ti wo lawujọ awọn osere tiata Yoruba nilẹwa Naijiria Alhaji Ayọbami Mudasir Olabiyi ti gbogbo aye mọ si Bobo B ti jade laye. Ti a ba n sọ nipa awujọ awọn gbajumọ osere tiata eekan ni Alhaji Mudasir Olabiyi Bobo B. Iroyin iku gbajumọ osere naa lo …
Ka si »Ikú lèrè ẹ̀sẹ̀, Adájọ́ dájọ́ ikú fáwọn ọ̀daràn adigunjalè marun un tó digunjalè ni banki kan lọffa, ọ́dún mẹ́fà sẹ́yìn.
Lẹyin ọdun mẹfa sẹyin ti isẹlẹ ikọlu idigunjale kan sẹlẹ nilu ọffa eyi ti okiki rẹ kan nipinlẹ kwara ati yika orileede Naijiria latari ọpọ ẹmi ti o sofo lati ọwọ awọn ọdaran adigunjale naa. Adajọ Haleema Salman ti ile ẹjọ giga ilu Ilorin nipinlẹ Kwara ti sọ pe ki …
Ka si »Ogójì làwọn Musulumi tókú nínú Ijamba ọkọ̀ lásìkò tí wọ́n ń rìnrìn àjò lọ fún ayẹyẹ ọjọ́ ìbí Anọbi.
Ogunlọgọ awọn eeyan ẹlẹsin Musulumi lo jẹ Ọlọrun nipe ninu ijamba ọkọ kan to waye lọjọ Aje Monday. Awọn olujọsin naa ni iroyin sọ pe o n rinrinajo lọ fun ayẹyẹ ọjọ ibi Anọbi, ninu ọkọ bọọsi J5 kan, niluu Saminaka, nipinlẹ Kaduna. Iroyin sọ pe ọkọ akẹru nla kan …
Ka si »