Agbabọọlu fun orileede wa Naijiria ati ilẹ Atalanta ni Italy, Ademola Lookman lo ti gba ami ẹyẹ gẹgẹ bi agbabọọlu to dara julọ nilẹ adulawọ Africa f’ọdun 2024. Lookman ẹni ọdun mẹtadinlọgbọn ọhun lo fi ẹyin awọn alatako rẹ lati Cote d’Ivoire, Brighton, Hove Albion, Simon Adingra, Serhou Guirassy lati …
Ka si »O ma se o, Kìnìún fa òṣìṣẹ́ ileewe giga fáṣítì OAU ya perepere lẹ́yìn ọdún mẹ́sàn-án tó ti ń fún-un loúnjẹ jẹ
Ọjọ buruku esu gbomi mu lọ naa jẹ fun akekoo ati awon oluko ̣l’ọgba Ile iwe giga Obafemi Awolowo fasiti Ile Ifẹ pẹlu bi Kinniun ọlọdun mẹsan kan se kọlu ẹni to n tọju rẹ to si gbemi lenu re. Gege bi iroyin naa se se lalaye, oloogbe Ọlawuyi Ọlabọde …
Ka si »