Iroyin pajawiri

Ètò Ọrọ̀-Ajé

Ó dójú ẹ o, Àjọ EFCC kéde ìyàwó Emefiele ati àwọn mẹ́ta mìíràn gẹ́gẹ́ bí ẹni tí wọ́n ń wá

Àjọ tó ń gbógunti ìwà àjẹbánu-isowo ilu basubasu nílewa Nàìjíríà, Ajọ EFCC ti kéde ìyàwó gómìnà àná fún banki Apapọ ilewa CBN l’Orileede Nàìjíríà, Godwin Emefiele, Margaret Dumbiri Emefiele ni wọn ti kede rẹ gẹ́gẹ́ bí ẹni tí wọ́n ń wá. Margaret Emefiele àti àwọn mẹ́ta mìíràn, òṣìṣẹ́ banki Apapọ …

Ka si »

Ó ti dójú ẹ bayi Àwọn Oníṣòwò ‘Bureau de change’ dáwọ iṣẹ́ dúró ní Abuja latari Ọ̀wọ́ngógó owo Dọ́là l’Orileede Naijiria

Ẹka awọn to n ṣowo paṣiparọ owo t’awon eeyan mọ si Bureau de Change nilẹwa Naijiria awọn onisowo naa to wa nilu Abuja, olu ilu ilẹwa l’Orileede Naijiria ti kede pe awọn yoo dawọ iṣẹ duro. Idi ti wọn lawọn fẹ tori rẹ ṣe bẹẹ ni nitori ọwọngogo dọla to …

Ka si »