Iroyin pajawiri

Ètò Ọrọ̀-Ajé

Lọdún 2025 yi àdínkù yóò débá ọ̀wọ́ngógó to n koju ilẹwa Nàìjíríà – Ààrẹ Bọla Tinubu lo sọ bẹ.

Lọdún 2025 yi àdínkù yóò débá ọ̀wọ́ngógó to n koju ilẹwa Nàìjíríà – Ààrẹ Bọla Tinubu lo sọ bẹ. Ààrẹ ilẹwa Naijiria Bola Ahmed Tinubu ti kéde láti ṣe ìdásílẹ̀ iléeṣẹ́ kan, ti o pe ni National Credit Guarantee Company lójúnà àti mójútó ìpèníjà táwọn èèyàn ọmọ Nàìjíríà ń kojú …

Ka si »

Ògbómọ̀sọ́ Ajílété Cradle Carnival, àkọ́kọ́ irú ẹ̀ nílu Ògbómọ̀sọ́ fakọyọ.

Nse nita pe tero pe tẹsẹ o si gbero nibi Asekagba eto ayẹyẹ ọdun ibilẹ Ògbómọ̀ṣọ́ Cradle Carnival to waye l’ọjọ aje Mọnde, ọjọ kẹtalelogun, osu Kejìlá ọdún 2024 yi ni papa igbabọọlu Sọun Township Stadium. Ṣaaju ki eto asekagba naa to bẹrẹ ni rabajigan ni awọn aṣaju ẹṣin mẹta, …

Ka si »

NCC ti pàsẹ́ fún Iléesẹ́ MTN láti sí àwọn Simu tí wọ́n tí padà

Ojú òpó ìbára ẹni sọ̀rọ̀ Nomba Simu yin gbọdọ̀ ti maa sisẹ́ padà látàri àsẹ tí àjọ NCC pa fún àjọ MTN Àjọ tó ń mójútó àwọn iléeṣẹ́ ìbánisọ̀rọ̀ lorileede Nàìjíríà, àjọ NCC ti darí àwọn iléeṣẹ́ ìbánisọ̀rọ̀ láti ṣí ojú òpó àwọn oníbàárà wọn tí wọ́n ti wọn dena …

Ka si »

Ọ̀ọ̀ni Ilè Ifẹ̀ f’òfin de àwọn lẹ́gbẹ́lẹ́gbẹ́ àt’àwọn tó n ta ọ̀wọ́n gógó Ata láwọn ọjà gbogbo tó wà nilu Ilé Ifẹ̀.

Ọọni Ile Ifẹ, Ọba Adeyeye Enitan Ogunwusi Ọjaja ll lo ti fòfin dè awọn Ẹlẹgbẹjẹgbẹ-Ọlọja ni gbogbo ọja nilu ile-Ifẹ patapata poo. O ni ka fẹgbẹ mu ni, ka fofin deni ko si n to jọ bẹ mọ laarin áwọn ọja gbogbo nilu ile-Ifẹ. Igbesẹ yi lo waye lẹyìn tí …

Ka si »

Hon. Adédoyin ro Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ láti sètò ìrànwọ́ fún àwọn ojúlówó Àgbẹ̀ pẹ̀lu bí òjò se n múra àti bẹ̀rẹ̀.

Olórí ọmọ ilé ìgbìmọ̀ Asòfin tí o pọ̀jù lọ nile igbimọ asoju sofin ipinlẹ Ọyọ Hon. Sanjọ Adedoyin lo ti parọwa si ijọba ipinlẹ Ọyọ lati gbaruku ti awọn agbẹ to n sisẹ ọgbin lasiko asẹlulẹ ojo yii. Hon. Sanjọ Adedoyin ẹni ti i soju ijọba Ibilẹ̵ Guusu Ogbomọsọ sọrọ …

Ka si »