Iroyin pajawiri

Ètò Ẹ̀kọ́

Èyi ni ohun ti o sokùnfa ohun tí àwọn ọmọ ìsọta fi sèkọlù sílèewe Girama Àrẹàgò l’Ogbomọsọ.

Ti a o ba gbagbe a o rántí pé, wàhálà oun rogbodiyan kan waye laipẹ yi nileewe Arẹago, l’Ogbomọsọ latari bi awọn ọmọ isọta kan se sekọlu s’awọn Akẹẹkọ ati awọn Olukọ nileewe naa. Wàhálà oun rogbodiyan ọhun to waye lo mu ki awọn Akẹẹkọ ati awọn Olukọ nileewe naa …

Ka si »

Ọdún kan lórí àpèrè Sọ̀ún tilẹ̀ Ògbómọ̀sọ́, Òrumọgẹ Football Competitiọn ni wọ́n fẹ̵ fi se

Se ọjọ ni pẹ ipade ki i jina, Eto ayẹyẹ ọdun kan lori itẹ Alayeluwa Ọba Ghandi Afọlabi Ọlaoye Orumọgẹgẹ kẹta Sọun tilẹ Ogbomọsọ ko pẹlu ibẹrẹ idije ere bọọlu alafẹsẹ gba Orumọgẹ Football Completion. Kabiesi Ọba Ọlaoye lo gori itẹ lọjọ kẹjọ osu kẹsan ọdun 2023 nipasẹ awọn igbimọ …

Ka si »

Ìjọba Àpapọ fòfin dè Ọmọ tí kò bá tí ì pé ọdún méjìdínlógún lati wọ ileewe gíga ni Nàìjíríà.

Ijọba apapọ orilẹede wa Naijiria ti fòfin dè awọn ọmọ ti ko ba ti i pe ọdun mejidinlogun (18) lati wọ ileewe giga nilẹ Naijiria. Minisita fun eto ẹkọ lorilẹede wa Ọjọgbọn Tahir Mamman lo sọ eyi di mimọ niluu Abuja l’Ọjọbọ Toside, ọjọ kejidinlogun, oṣu keje ọdun 2024. Nibi …

Ka si »

Ẹ máa mu’gbo lọ, ìjọba Oríléèdè Germany buwọ́lu òfin tó faramọ igbó fífà bẹ̀rẹ̀ lọ́jọ́ kíní oṣù Kẹrin, Ọdún yii.

April Fool kọ o, ẹ maa fagbo lọ, ijọba Orileede Germany lo jan lonte bẹ. Awọn eeyan orileede Germany kan wa to jẹ pe wọn kundun lati maa fagbo lẹyin ti wọn ba pari iṣẹ oojọ wọn, ọti sini awọn mi nifẹ si lati mimu. Gbolohun naa lo jade lẹnu …

Ka si »

O ma se o, Kìnìún fa òṣìṣẹ́ ileewe giga fáṣítì OAU ya perepere lẹ́yìn ọdún mẹ́sàn-án tó ti ń fún-un loúnjẹ jẹ

Ọjọ buruku esu gbomi mu lọ naa jẹ fun akekoo ati awon oluko ̣l’ọgba Ile iwe giga Obafemi Awolowo fasiti Ile Ifẹ pẹlu bi Kinniun ọlọdun mẹsan kan se kọlu ẹni to n tọju rẹ to si gbemi lenu re. Gege bi iroyin naa se se lalaye, oloogbe Ọlawuyi Ọlabọde …

Ka si »