Monthly Archives: October 2024

Eyi ni ohun tó ṣokùnfà ikú gbajúmọ̀ òṣèré tíátà krìstẹ́nì Korede Are ‘Baba Gbenro

Ọpọ àwọn oloolufẹ lo ti wọn fẹ gbajumọ osere naa lo ti n ṣedaro Dokita Moses Korede Arẹ ẹni ti ọpọ èèyàn mọ si Baba Gbenro to doloogbe lana Ọjọbọ Thursday, ọjọ kẹrinla oṣu Kọkanla ọdun 2024 yii. Iyalẹnu nla ni iku gbajumọ osere kristiẹni ọhun Baba Gbenro jẹ fun …

Ka si »

Aunty Ramota bèèrè fún ìrànwọ́ owo lọ́wọ́ àwọn èèyàn ọmọ orileede Nàìjíria nótorí ìlera rẹ̀

O ma se o, Fọnran fídíò kan to jade loju opo itakun ayelujara Instagram lo ti ṣafihan bi gbajumọ oṣerebinrin onitiata nní, Ramota Adetu, ti ọpọ èèyàn mọ si Aunty Ramota ṣe n pe fun iranlọwọ àwọn eeyan ọmọ Naijiria pe oun ko ni ile lori mọ. Ninu fọnran fídíò …

Ka si »

Irọ́ ikú ni wọn npa o, Lagbaja ò kú, ó lọ fún ìsinmi lẹ́nu ìṣẹ̀ ni-Iléeṣẹ ológun kede bẹ

Ileeṣẹ ologun nilẹwa Naijiria ti wọgile iroyin ẹlẹjẹ kan to ni Ọga agba ologun lorilẹede Naijiria, Taoreed Lagbaja ti jade laye. Agbẹnusọ ileeṣẹ ologun, Onyema Nwachukwu fi ohun naa lede taki iroyin ẹlẹjẹ ti awọn kan ngbe kiri pe ọgagun naa ku, o ni Lagbaja lọ fun isinmi lẹyin iṣẹ, …

Ka si »

Akọni Ọmọ ni ọmọbìnrin mi tó d’ologbe, ikú rẹ bàmí lọ́kàn jẹ́ púpọ̀, Saidi Balogun sọ̀rọ̀ lórí ikú Zeenat Balógun ọmọ rẹ̀.

Gbajugbaja oṣere tiata Yoruba, Saidi Balogun, ti ṣapejuwe ọmọbinrin rẹ, Zeenat Balogun to ku laipẹ yii gẹgẹ bii akọni eeyan. Balogun sọrọ yii ninu atẹjade kan to fi sita loju opo Instagram rẹ lọjọ Aiku Sunday. Ni owurọ ọjọ Ẹti Friday, ọjọ karun un, oṣu Kẹwaa yii ni ilumọọka oṣere …

Ka si »

Wọ́n fìyà ẹ̀sẹ̀ àìmọ̀dí jẹ ọmọkùnrin ọmọ ọdún mẹ́rìnlá kan dójú àmì

Gẹgẹ bí iroyin ọhun ti a gbọ, awọn oṣiṣẹ at’awọn ẹsọ eleto-ààbò ṣọọṣi ọhun ti wọn ja lole ni wọn ti kọkọ lu ọmọdekunrin alaiṣẹ ọmọ ọdún mẹrinla ọhun lalubole-alubami ko to dipe Ojúlówó Ole gbewiri to se bẹ ji owo gbe ni sọọsi jẹwọ. Ọmọdekunrin, ọmọ ọdún méjìlá ọhun …

Ka si »