Monthly Archives: September 2024

Ikú lèrè ẹ̀sẹ̀, Adájọ́ dájọ́ ikú fáwọn ọ̀daràn adigunjalè marun un tó digunjalè ni banki kan lọffa, ọ́dún mẹ́fà sẹ́yìn.

Lẹyin ọdun mẹfa sẹyin ti isẹlẹ ikọlu idigunjale kan sẹlẹ nilu ọffa eyi ti okiki rẹ kan nipinlẹ kwara ati yika orileede Naijiria latari ọpọ ẹmi ti o sofo lati ọwọ awọn ọdaran adigunjale naa. Adajọ Haleema Salman ti ile ẹjọ giga ilu Ilorin nipinlẹ Kwara ti sọ pe ki …

Ka si »

Ogójì làwọn Musulumi tókú nínú Ijamba ọkọ̀ lásìkò tí wọ́n ń rìnrìn àjò lọ fún ayẹyẹ ọjọ́ ìbí Anọbi.

Ogunlọgọ awọn eeyan ẹlẹsin Musulumi lo jẹ Ọlọrun nipe ninu ijamba ọkọ kan to waye lọjọ Aje Monday. Awọn olujọsin naa ni iroyin sọ pe o n rinrinajo lọ fun ayẹyẹ ọjọ ibi Anọbi, ninu ọkọ bọọsi J5 kan, niluu Saminaka, nipinlẹ Kaduna. Iroyin sọ pe ọkọ akẹru nla kan …

Ka si »

Owá Obòkun Ilẹ̀ Ijẹsha, Ọba Gabriel Adekunle Arọ́mọlaran II wàjà lẹni ọdún mérìndínlaadọrun

Erin wo, ajanaku sun bi oke, Owa Obokun ti Ile Ijesha, Ọba Gabriel Adekunle Aromolaran ll niroyin fidiẹ mulẹ pe o ti waja lẹni ọdun mẹrindinlaadọrun un. Ìròyìn iku eekan ọba nilẹ Yoruba nipinlẹ Ọsun naa Ọwá Obòkun ti ilẹ Ijesha lo mi igboro titi l’ọjọbọ Toside, ti awọn ọmọ …

Ka si »

Ọdún kan lórí àpèrè Sọ̀ún tilẹ̀ Ògbómọ̀sọ́, Òrumọgẹ Football Competitiọn ni wọ́n fẹ̵ fi se

Se ọjọ ni pẹ ipade ki i jina, Eto ayẹyẹ ọdun kan lori itẹ Alayeluwa Ọba Ghandi Afọlabi Ọlaoye Orumọgẹgẹ kẹta Sọun tilẹ Ogbomọsọ ko pẹlu ibẹrẹ idije ere bọọlu alafẹsẹ gba Orumọgẹ Football Completion. Kabiesi Ọba Ọlaoye lo gori itẹ lọjọ kẹjọ osu kẹsan ọdun 2023 nipasẹ awọn igbimọ …

Ka si »

Olúgbọ́n fi àtìlẹyìn rẹ han fún Imaam àgbà ilẹ̀ Ògbómọ̀sọ́.

Olugbọn ti orile-igbọn Asaaju awọn awọn ori ade ọrun ilẹkẹ nijọba ibilẹ Suurulere nilu Ògbómọ̀ṣọ́, ipinlẹ Oyo, Ọba Francis Alao ti sọ gbángba-gbangba pe Awọn Ori-Ade ọrun-ilẹkẹ ko lagbara lori awọn Adari ẹṣin kankan nilẹ Yoruba ati bi gbogbo. Ọba Alao sọ eyi di mímọ nínú atẹjade kan to gba …

Ka si »