Iroyin pajawiri

Monthly Archives: July 2024

Ìgbòho lóní kí a bọ̀’gún a sì ti bọ́ o, o ni gbogbo àwọn tí wọ́n ba fẹ́ gbógunti iran Yorùba kí ògún se wọn síba sìbo.

Nilu Ogbomọsọ ati agbegbe rẹ, agbarijọpọ ẹgbẹ ọdẹ ibilẹ ati awọn eeyan ọmọ ọkọ Yoruba ti wọn fọnrere Ominira Yoruba Nation korajọpọ nidi ogun. Ohun ti wọn n pariwo sọ ni pe ogun lakaye Ọsimọlẹ, kolomi nle fẹjẹ wẹ, ko fẹjẹ wọn wẹ o, gbogbo awọn ti wọn fẹ gbogun, …

Ka si »

NCC ti pàsẹ́ fún Iléesẹ́ MTN láti sí àwọn Simu tí wọ́n tí padà

Ojú òpó ìbára ẹni sọ̀rọ̀ Nomba Simu yin gbọdọ̀ ti maa sisẹ́ padà látàri àsẹ tí àjọ NCC pa fún àjọ MTN Àjọ tó ń mójútó àwọn iléeṣẹ́ ìbánisọ̀rọ̀ lorileede Nàìjíríà, àjọ NCC ti darí àwọn iléeṣẹ́ ìbánisọ̀rọ̀ láti ṣí ojú òpó àwọn oníbàárà wọn tí wọ́n ti wọn dena …

Ka si »

Gomina Makinde, Sọ̀ún tilẹ Ògbómọ̀sọ́ yoo wa níbi àpérò fún ìdàgbàsókè ìlú Ògbómọ̀sọ́. OSDNA.

Ọna ara ni apero ati ayẹyẹ ọlọdọọdun ti awọn agbarijọpọ Ọmọ bibi ilu Ogbomọsọ l’Ọkunrin ati l’Obinrin toun gbe ni apa ariwa orileede Amẹrika, (Ogbomọsọ Sons and Daughters in North America) fẹ se lọdun yi. Gomina Ipinlẹ Ọyọ, Onimọ ẹrọ Seyi Makinde, Sọun tilẹ Ogbomọsọ, Alayeluwa, Ọba Ghandi Afọlabi Ọlaoye …

Ka si »

Òsì Balógun tilẹ̀ Ìbàdàn, Ọba Lateef Gbadamọsi Adebimpe ti wàjà o.

Oloogbe naa Osi Balogun tilẹ Ibadan, Ọba Lateef Gbadamọsi Adebimpe j’Ọlọhun nipe ni ọjọru Wednesday, ọjọ kẹrinlelogun lẹyin aisan ranpẹ ti wọn lo n se e. Gẹgẹ bi iroyin naa ti ileesẹ iwe iroyin Naijiria Tribune gbe jade, ologbe naa lo soju Ọba Olubadan tuntun Ọba Owolabi Ọlakulẹyin lasiko sisi …

Ka si »

Ìjọba Àpapọ fòfin dè Ọmọ tí kò bá tí ì pé ọdún méjìdínlógún lati wọ ileewe gíga ni Nàìjíríà.

Ijọba apapọ orilẹede wa Naijiria ti fòfin dè awọn ọmọ ti ko ba ti i pe ọdun mejidinlogun (18) lati wọ ileewe giga nilẹ Naijiria. Minisita fun eto ẹkọ lorilẹede wa Ọjọgbọn Tahir Mamman lo sọ eyi di mimọ niluu Abuja l’Ọjọbọ Toside, ọjọ kejidinlogun, oṣu keje ọdun 2024. Nibi …

Ka si »