Iroyin pajawiri

Monthly Archives: June 2024

Ìjà lódé lorin d’òwe o, Kòsí n to burú níbẹ̀ bí Ààfin Sọ̀ún tilẹ̀ Ògbómọ̀sọ́ bá kọ̀we ẹ̀sùn sọwọ́ sí Imaam lórí bi o ti rìnrìn àjò láìsọ fún Ọba.

Awọ aarin Imaam agba ilẹ Ogbomọsọ ati idile Ayilara to se bẹ di wahala di ti Ọba Ṣọun tilẹ Ogbomọṣọ lo tun ti n b’ọna miran rugbo bọ yi o. Awọ oun dukuu naa lotun ti di awuyewuye bayi o Gẹgẹ bi Iroyin kan ti a gbọ pe Kabiyesi Ọba …

Ka si »

Davido àti Chioma s’ègbéyàwó nísu lọ́kà, ò dùn, ó lárinrin Chivido 2024 ni wọ́n n pe àkọlé ayẹyẹ ìgbéyàwó náà.

Ọjọ Iṣẹgun Tuesday, ọjọ karundinlọgbọn, oṣu Kẹfa, ọdun 2024 yi ni ayẹyẹ igbeyawo naa waye laarin gbajugbaja ilumọnka olorin takasufe, David Adeleke ti ọpọ mọ si Davido, ati afẹsọna rẹ, Chioma Rowland. Ṣaaju ikede ayẹyẹ igbeyawo naa ni iroyin kan ti saaju gbe jade pe Chioma ati Davido ti ṣe …

Ka si »