Iroyin pajawiri

Monthly Archives: May 2024

Kòs’ógun mọ́, kò sọ́tẹ̀ mọ́ o, ìjà parí láàrin Yinka Quadri̧ ati Ògògó ọmọ kúlódò.

Nise ni ẹnu ya ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn nígbà tí ìròyìn gbòde pé àwọn àgbà òṣèré tiata Yoruba Yinka Quadri àti Taiwo Hassan tí ọ̀pọ̀ mọ̀ sí Ogogo ti parí ìjà. Ìbéèrè tó gba ẹnu ọ̀pọ̀ èèyàn ni pé ṣe àwọn méjéèjì ń jà tẹlẹ ni. Ṣáájú ni àwọn ìròyìn kan ti …

Ka si »