Iroyin pajawiri

Monthly Archives: April 2024

Hon. Ògúnwuyì gbé Asia ẹgbẹ́ lé àwọn olùdíje dupò Alága ìjọba ìbílẹ̀ l’Ogbomọsọ lọ́wọ́, Oyèdókun Timothy àti àwọn olùdíje yoku gba Asia ẹgbẹ́ náà.

Saaju eto idibo Alaga ijọba ibilẹ ti ipinlẹ Ọyọ ti yoo waye lọjọ Kẹtadinlogun 27 Osu kẹrin ti a wa ninu rẹ yi, ẹgbẹ oselu Ọlọburẹla PDP nipinlẹ Ọyọ seto gbigbe Asia ẹgbẹ le awọn oludije nijọba ibilẹ kọọkan lọwọ. Eto gbigbe Asia ẹgbẹ le awọn Oludije lọwọ naa ti …

Ka si »

Ipa tí Ààrẹ Musulumi, ìdíle Owodunni ko nínú ẹ̀sìn Islam kọjá kí Imam Àgbà ilẹ̀ Ògbómọ̀sọ́ o ma yẹpẹrẹ rẹ̀.

Awọn agbarijọpọ akẹkọọ jade nile kewu Akhbarudeen Institute Ogbomọsọ, nipinlẹ Ọyọ ti nawọ ikilọ fun Imam Agba ilẹ Ogbomọsọ lati Sheikh Taliat Yunus Ayilara dakẹ yiyẹpẹrẹ Aarẹ Musulumi ilẹ Ogbomọsọ, Alhaji AbdulGaniyu Owodunni. Inaka ikilọ naa lo jẹ jade ninu atẹjade kan ti awọn agbarijọpọ akẹkọọ jade nile Kewu ọhun …

Ka si »

Ọ̀rọ̀ burúkú re nígboro ẹnu, Mo fẹ́ mọ̀ bóyá nǹkan ọmọkùnrin mi ń ṣiṣẹ́ dáadáa ni mo ṣe bá ọmọ ọdún mẹ́ta lòpọ̀

Ọwọ ileesẹ ọlọpaa nipinlẹ Ọyọ, ti ba ọkunrin kan ẹni ọdun mejilelogun Farouk, fun ẹsun pe o fi ipa ba ọmọdebinrin ọmọ ọdun mẹta lopọ. Agbegbe Popo Yemoja nilu Ibadan, ni isẹlẹ naa tigbe sẹlẹ ni alẹ Ọjọbọ Tọside ti o kọja. Gẹgẹ bi iwe iroyin Nigerian Tribune ti salaye, …

Ka si »

Èemọ́n re o, Igbákejì Ọ̀ga Àgbà Ọlọ́pàá, Deputy Commissioner of Police pokùnso, sekúpara rẹ̀ nílu Ògbómọ̀sọ́.

Iyoku ara oku igbakeji ọga agba ọlọpaa naa ni wọn ba ninu ilegbe rẹ nibi ti o pokunso si ninu ilegbe rẹ. Ologbe naa ẹni ti i se igbakeji ọga agba ọlọpaa ti wọn pe orukọ rẹ ni Gbọlahan Oyedemi aladugbo rẹ sọ pe o danikan wale fun ayẹyẹ ọdun …

Ka si »

Ẹ máa mu’gbo lọ, ìjọba Oríléèdè Germany buwọ́lu òfin tó faramọ igbó fífà bẹ̀rẹ̀ lọ́jọ́ kíní oṣù Kẹrin, Ọdún yii.

April Fool kọ o, ẹ maa fagbo lọ, ijọba Orileede Germany lo jan lonte bẹ. Awọn eeyan orileede Germany kan wa to jẹ pe wọn kundun lati maa fagbo lẹyin ti wọn ba pari iṣẹ oojọ wọn, ọti sini awọn mi nifẹ si lati mimu. Gbolohun naa lo jade lẹnu …

Ka si »