Monthly Archives: April 2024

Bàbá mi kò lórúkọ́ k’áwọn èèyàn o to dìbò yan mi, nítorí nàà mo ti fòpin sí óṣèlú ‘ta a ni bàbá rẹ’ nipinlẹ Ọ̀yọ́

Gomina ipinle Ọyọ, Onimọ-ẹrọ Ṣeyi Makinde sọ pe ori oun ni opin ti de ba oṣelu ‘ta a ni baba rẹ’ nipinlẹ Ọyọ eyi to ti maa n ṣẹlẹ tipẹtipẹ. Makinde sọ pe oun ti fopin si i pẹlu ijawe olubori oun gẹgẹ bii gomina Ipinlẹ Ọyọ nigba meji lai …

Ka si »

Náwó náwó e s’àpà o, o ni ẹ̀gùn to n maa n gun ìran Yorùbá to ma n m’ori wa wú láti náwó lágbo, Oluwo si àjọ EFCC.

Náwó náwó e s’àpà o, o ni ẹ̀gùn to n maa n gun ìran Yorùbá to ma n m’ori wa wú láti náwó lágbo, Oluwo si àjọ EFCC. Oluwo tilu Iwo, Oba Abdulrosheed Adewale Akanbi, ti sọrọ nipa awuyewuye ọrọ to n lọwọ yi ti o niise nipa ẹsun titabuku …

Ka si »

Èyí o wù ẹ wí t’Olúwa làsẹ o, Ẹni yóówù tó bá gbógun tì ọ́, gbógun ti Ọlọ́run Ọba ni o, Oluwo lo sọ bẹ fún Soun tìlú Ògbómọ̀sọ́.

Oluwo tilu iwo, Oba Abdulrasheed Adewale Akanbi Telu kinni, l’ọjọ Abamẹta Satiide sọrọ atilẹyin rẹ fun Soun tile Ogbomoso, Oba Ghandi Afolabi Olaoye Orumogege lll, lasiko ti o sabẹwo si laafin rẹ l’Ogbomọsọ. Oluwo nigba to n sọrọ rẹ, sasọtẹlẹ pe, Ẹnikẹni yoowu to ba dide ogun si Oba Ghandi, …

Ka si »

OOT gẹ́gẹ́ bi Alága Ìjọba Ìbílẹ̀ guusu Ògbómọ̀sọ́ lẹ́ẹ̀kansi kì í se àsìyàn – AFOO ló sàlàyé ọ̀rọ̀ bẹẹ

Oludije fun ipo Alaga Ijọba ibilẹ Guusu Ogbomọsọ labẹ ẹgbẹ oselu Action Democratic Party ADP nigbakan Hon. Afọlabi Olushọla ti ọpọ eeyan mọ si AFOO ni o ti fi ọwọ ẹ sọya sọ fun gbogbo eeyan pe alaga ijọba ibilẹ guusu Ogbomọsọ lọwọ bayi ti o tun jẹ oludije fun …

Ka si »

Ọwọ tẹ àwon Afurasí ajìjàgbara Odua Nation mérìndínlógún pẹ̀lú ohun ìjà olóró lakoko ti won ya wọ ọgbà ọ́fìsì Gómìnà ipinlẹ Oyo

Niise l’awọn Eeyan kan ti won furasi pe wọn jẹ ọmọ ẹgbẹ Ajijagbara Oodua Nation yawọ inu Ọfisi Gomina nilu Ibadan tiise Olu-ilu ipinle Oyo l’owurọ ọjọ Abameta Satide, ojo ketala, osu kerin, odun 2024 ti a wa yi. Awọn ajijagbara naa ni wọn tun yawọ ile igbimọ aṣofin Oyo, …

Ka si »

Zack Orji o ku o, E yé gbé ìròyìn eléjè kiri – Ààre ẹgbẹ́ àwọn òsèré kùnrin elédè òyìnbó, ìyen Actors Guild of Naijiria AGN, Emeka Rollas lo pariwo síta bẹ.

Lẹnu nkan bi ọjọ mẹta yii ni awuyewuye gba ori itakun-ayelukara kan, pe gbajumọ osere-tiata ọmọ Igbo nni, Zack Orji, ti dagbere f’aye. Eyi ri bẹẹ latari iṣẹ abẹ kan ti wọn kede pe ọkunrin naa nilo lati ṣe ni kiakia, nitori ara rẹ ti ko le lẹnu lọọlọ yii. …

Ka si »